Aarẹ Bola Tinubu n ṣedaro Segun Awolowo, ọmọ-ọmọ Baba Obafemi Awolowo to jade laye lẹni ọdun mejilelọgọta. Ninu atẹjade kan ti oludamọran aarẹ lori ọrọ iroyin, Bayo Onanuga, fi sita ni Aarẹ Tinubu ti ...
Chimamanda Ngozi Adichie n ṣe daro awọn obi rẹ ti wn jade laye laarin ọdun kan. Oṣu Kẹfa, ọdun 2020 ni baba rẹ, James Adichie jade laye lẹni ọdun mẹtadinladọrun ni ileewosan to ti n gba itọju lẹyin to ...